Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)

Follow Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)
Share on
Copy link to clipboard

Alaye waye ninu waasi yi nipa bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ti se ki irun bi osan ba di oru ni oju aye re pelu awon idajo irun yii. Oro si tun waye lori wipe oorun ati osupa ninu awon amin agbara Olohun ni won wa, won kii wo okunkun nitori iku eniyan kan tabi wiwa laaye re.

Sharafuddeen Gbadebọ Raji


    • May 18, 2014 LATEST EPISODE
    • infrequent NEW EPISODES
    • 51m AVG DURATION
    • 1 EPISODES


    More podcasts from Sharafuddeen Gbadebọ Raji

    Search for episodes from Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf) with a specific topic:

    Latest episodes from Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)

    Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)

    Play Episode Listen Later May 18, 2014 51:08


    Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)

    irun idaj

    Claim Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)

    In order to claim this podcast we'll send an email to with a verification link. Simply click the link and you will be able to edit tags, request a refresh, and other features to take control of your podcast page!

    Claim Cancel