Having a new life in Christ and taking your relationship with Him one day at a time, to the next level.....
D'arapo mo wa l'ati tesiwaju wiwo oro Olorun (bibeli) gege bi ipese itosona ti igbalode ti a gbe kale fun Kristieni l'oni nigbati a o ma ko eko pata l'ati inu iwe awon oba keji(2 kings) ati Nehemiah
Join us as we bring this topic/series to a close, learning from what happened to the Israelites in 1 Samuel 4
Bi nkan ko ba je ti atijo/igbaani, a si je ti igbalode sugbon kini eto ero irinna ti igbalode ti Olorun pese fun wa loni?
Is it possible to have access to food and water(drink) and still starve or become dehydrated?
Ohun kan ni Israeli ni l'ati se bi won ba fe ki 'ero ijinle ti igbaani' mu won gunle si ebute yiyanju eyun ni ile ileri won. D'arapo mo wa lowuro yi nigbati a n tesiwaju wiwo bi ero oun ti n sise
Join us for a time in God's presence as we search the scripture
Kini iru ero ijinle ti o dari irin-ajo awon ara igbaani? Bawo ni ero oun ti n şise?
Today, let's look at the role of Aaron and Hur as a support system for Moses/all Israel that brought about the defeat of their enemy, the Amalekites. Exodus 17: 8-13....join us and let's study
Nje o mo ohun ti èro yi je ati bi o ti n şişé? D'arapo mo wa fun alaye kikun l'ori re nigbati a o ka iwe orin-Dafidi l'ati ki alaye wa l'ehin....(Psalm 16:8&9)....
Join us friends as we start our study and series with an interesting topic. Who is/are support systems?
D'arapo mo wa òré fun idupe ati adura nigbati a o maa yin Olorun pelu orin ope, ti a o si tun fi irin-ajo wa le e l'owo fun odun titun. E je ki a gbadura;
A ku odun, a ku iyedun. Odun a y'abo fun wa. Oju wa yoo si ma r'odun l'oruko Jesu Kristi. Amin!
We invite you this morning to join us for special Christmas episode as we put CHRIST at the centre of our celebration. Happy Christmas Reviewers!
E je ki a wo imoran ti Poolu ati Solomoni gba wa ninu iwe Filipi ati iwe Owe, ki a wa to tesiwaju l'ati wo ida keji aroye/irahun ninu iwe Orin-Dafidi ori aadota {Psalm 50:14&15}. A ku ipalemo odun, yoo ba wa l'ayo...
Have you ever thought about what the the first Christmas was like?
Nje o ti e je eniyan tii ma s'aroye? Bi o ba fe mo, gbiyanju l'ati d'arapo mo wa fun eko yi ki o le mo ohun ti aroye tumo si ati pe boya o ti tibe d'eşe
What makes the believer's new life possible is the change that happens within by the power of the Holy Spirit. He works on the inward(heart) part of the believer and that, gradually works it's way out. But what exactly does the circumcised heart looks like?
A o mu eko yi wa s'opin l'oni nigbati a o maa wo: "jije omo agbo ile igbagbo" fun igba ikehin....d'arapo mo wa...
Today, we go into the gospels to see how Jesus used the concept of farming to describe a fruitful or productive Christian life as we relate it to the heart of the believer...John 15:1-4,....5.....
A n tesiwaju l'ati maa wo awon anfaani to wa ninu jije omo agbo ile igbagbo nigbati a o maa ka ise awon aposteli(Acts 1:12-14, 2:1-4) ni wiwo bi awon omo ehin ti gba ileri naa ti a se fun won ni kikun....
Let's go back to Romans chapter 2 to see how the old testament laws and beliefs relate to chriatianity as explained by Paul. Romans 2:17-25,29. Is Paul talking to or about you and i??
E je ki a tesiwaju l'ati maa wo ona abayo ti a pe ni jije omo agbo ile igbagbo....
I don't know about you or if you have noticed too, that there are so many metaphorical sayings, phrases and statements made in the bible. Over the years of my study of the word, i have enjoyed reading them. Let's look at one of them on this series; The Circumcised Heart. Join us and let's study together
Jije omo agbo ile igbagbo ni ona abayo miiran ti a o bere si ni wo l'ati oni titi a o fi pari èkó yii tori bi o ti şe pataki to....E maa ba wa kalo....
Although Jesus had called a child to himself to reference what he was teaching the disciples in Matthew 18:6, but whatelse does "one of these" mean? or "these little ones"?
E jé kí á tèsíwájú l'ati máa wo awon ona abayo miiran si ipadanu fun ipongbe ti emi nigbati a o ka Heberu ori kejila(Hebrews 12:1-3).....
Paul's words in 1 Corinthians 11:1 can jump out to us differently and we may have different questions.....but why don't you join us as we review that verse together and also look at other things
Kini awon ohun naa ti a le e şe l'ati da ipongbe wa fun Olorun tabi awon ohun ti emi pada?
Antioch, the largest city in the Roman world was where the disciples were given the name that has stuck till date (Christian). What brought about this name given by the gentile believers?
E je ki a wo okan si ninu awon ohun ti o le e faa ki eniyan padanu ipongbe fun Olorun ki a to bere l'ose to n bo l'ati maa wo awon ohun ti a le e şe fun ona abayo
Is living the Jesus' way of life possible for anyone?
A o tesiwaju l'ati maa wo ohun miiran ti o tun lee şe okunfa ki onigbagbo padanu ipongbe fun Olorun nigbati a o maa ka l'ati inu iwe Jobu 13....
After Jesus' baptism and his wilderness experience (that is when he was tempted by the tempter), he began to call men together for discipleship....why was this mission so important?
Ki ni ipongbe ti emi? Awon ona wo ni o se e se ki a gba padanu re? D'arapo mo wa l'ati dahun awon ibeere wonyi ati bee bee lo.....
Today, as we begin a new series; let's look at what discipleship is and who a disciple is plus where it all began and why(that is the need for it). Deuteronomy 6:6&7.....20
Ni ipele àkókó èkó wa titun yii ni a ko wo ohun ti ipadanu fun ikundun/idalorun fun oun jije ati mimu je pelu anfaani re ni ago ara ki a to bo si ipele ti emi....e maa ba wa kalo....
Join us as we round up this series by looking at our ordinary feelings of putting ourselves in the position of "not deserving" that is when we can't see past our limitations and weaknesses....
D'arapo mo wa l'ati mu eko yii wa s'opin nigbati a o maa ka iwe işe awon aposteli l'ati ko èkó pataki l'ara Barnaba(Acts 9:26-30) ti o mu ipin/ipe şe nipa şişe ohun ti o bu ola fun Oluwa ni aini ariwo ninu....
Before we dive into today's message, I'll like to take a few moment to explain what the topic for our series is not(does not mean) as we have looked at what it means up till now and continues today....please stay with us, let's study together....
Opo eniyan lo wa ninu aye ti won ru oyun ara kiri sugbon ti won ko ri i bi tabi ti won ti şe isinku ait'ojo fun talenti/ara ti a fi si won ninu gege bi okunrin to wa ni Matiu(25) orikarun-din-l'ogbon ti şe...kini o fa a
Do you sometimes look around you and feel as though some people are too cruel, wicked or mean and do not deserve even an iota of God's mercy and love?
Nje o ti bi ara re ni iru ibeere akinkanju béè ri? Kini idi iwalaaye mi tabi awon ohun naa ti a da mi l'ati şe? Nje mo n mu ipin/ipe şe?
Still in the book of Act, let's look at another story of God's power and sovereignty that tells and shows us that; "....God shows no favouritism" Act 10:34.....or a respecter of persons...join us and let's study together
Nje o ti d'igba ronu idi re ti a fi maa ba ijakule pade tabi ti awa naa fi n ja elomiran kule
Why are we sometimes disappointed with God's choice of people and things?We're starting from a good place in the book of Acts (9:10-19).....join us as we review the word together
Pupo ninu wa ni yoo ma koju iru ijakule to le koko bi ti Josefu ninu irin-ajo aye l'eyi ti o tun le e ba wa l'ojiji pelu. Sugbon kini a le e şe bi a ba ba ara wa ni iru ipo yi?
Why is there sometimes a slow move when God knows what to do?
Nibo tun ni ijakule ti le dide tabi wa ninu irin-ajo aye?
Appointed by God and anointed(when he was very young), David spent a long(infact very long) time in God's training camp and still did not become king over all Israel after Saul's death. Join us as we review some of the things he learned that equipped and helped shape him to be the kind of leader(king) that God wanted...
Ni ose ti o koja ni a wo ranpe nipa irin-ajo Samueli lo si Şilo ni ile alufaa Olorun, Eli.....Iru apeere/awokoşe wo ni Eli ati awon omo re mejeeji je si Samueli? Bawo ni Samueli ti koju ijakule re ni abe orule won?